Hágáì 1:2 BMY

2 Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: “Àwọn ènìyàn wọ̀nyí wí pé, ‘Kò ti to àkókò láti kọ́ ilé Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin Hágáì 1

Wo Hágáì 1:2 ni o tọ