Jónà 1:13 BMY

13 Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin náà wà á kíkan láti mú ọkọ̀ wà sí ilẹ̀: ṣùgbọ́n wọn kò lè ṣe é: nítorí tí òkun túbọ̀ ru síi, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle sí wọn.

Ka pipe ipin Jónà 1

Wo Jónà 1:13 ni o tọ