Jónà 1:4 BMY

4 Nígbà náà ni Olúwa rán ìjì ńlá jáde sí ojú òkun, ìjì líle sì wà nínú òkun tóbẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ náà dàbí ẹni pé yóò fọ́.

Ka pipe ipin Jónà 1

Wo Jónà 1:4 ni o tọ