Málákì 1:10 BMY

10 “Hó ò! Ẹnìkan ìbá jẹ́ wà láàrin yín ti yóò sé ìlẹ̀kùn tẹ́ḿpìlì, pé kí ẹ má ba à ṣe dá iná asán lórí pẹpẹ mi mọ́! Èmi kò ní inú dídùn sí i yín,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, “bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò gba ọrẹ kan lọ́wọ́ ọ yín.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:10 ni o tọ