Málákì 1:11 BMY

11 Orúkọ mi yóò tóbi láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, láti ìlà-oòrùn títí ó sì fi dé ìwọ̀ oòrùn. Ní ibi gbogbo ni a ó ti mú tùràrí àti ọrẹ mímọ́ wá fún orúkọ ọ̀ mi, nítorí orúkọ mi tóbi láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:11 ni o tọ