Málákì 1:12 BMY

12 “Nítorí ẹ̀yin ti sọ ọ́ di àìmọ́, nínú èyí tí ẹ wí pé, ‘Tábìlì Olúwa di àìmọ́ àti èso rẹ̀,’ àní oúnjẹ́ rẹ̀ ni ohun ẹ̀gàn.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:12 ni o tọ