Orin Sólómónì 4:11 BMY

11 Ètè rẹ ń kán dídùn afárá oyin, ìyàwó mi;wàrà àti oyin wà lábẹ́ ahọ́n rẹ.Òórùn aṣọ rẹ sì dàbí òórùn Lébánónì.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4

Wo Orin Sólómónì 4:11 ni o tọ