Orin Sólómónì 4:4 BMY

4 Ọrùn rẹ dàbí ilé ìṣọ́ Dáfídì,tí a kọ́ pẹ̀lú ìhámọ́ra;lórí rẹ̀ ni a fi ẹgbẹ̀rún àpáta kọ́,gbogbo wọn jẹ́ àṣà àwọn alágbára.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4

Wo Orin Sólómónì 4:4 ni o tọ