Orin Sólómónì 4:6 BMY

6 Títí ọjọ́ yóò fi rọ̀tí òjìji yóò fi fò lọ,Èmi yóò lọ sí orí òkè ńlá òjíáàti sí òkè kékeré tùràrí.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4

Wo Orin Sólómónì 4:6 ni o tọ