Orin Sólómónì 4:8 BMY

8 Kí a lọ kúrò ní Lẹ́bánónì, ìyàwó mi,ki a lọ kúrò ní Lẹ́bánónì.Àwa wò láti orí òkè Ámánà,láti orí òkè ti Ṣénírì, àti téńté Hérímónì,láti ibi ihò àwọn kìnnìún,láti orí òkè ńlá àwọn ẹkùn.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4

Wo Orin Sólómónì 4:8 ni o tọ