Orin Sólómónì 5:1 BMY

1 Mo ti dé inú ọgbà mi, arábìnrin mi, ìyàwó mi;mo ti kó òjíá pẹ̀lú òórùn dídùn mi jọ.Mo ti jẹ afárá mi pẹ̀lú oyin mi;mo ti mu ọtí wáìnì mi pẹ̀lú wàrà mi.Ẹ jẹ, ẹ̀yin ọ̀rẹ́, ẹ mu,àní ẹ mu àmuyó, ẹ̀yin olùfẹ́

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 5

Wo Orin Sólómónì 5:1 ni o tọ