Orin Sólómónì 5:15 BMY

15 Ẹṣẹ̀ rẹ̀ rí bi i òpó mábùtí a gbé ka ihò ìtẹ̀bọ̀ wúrà dáradáraÌrísí rẹ̀ rí bí igi kédárì Lẹ́bánónì,tí dídára rẹ̀ kò ní ẹgbẹ́.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 5

Wo Orin Sólómónì 5:15 ni o tọ