Orin Sólómónì 8:1 BMY

1 Ìwọ ìbá rí bí arákùnrin misí mi èyí tí ó mú ọmú ìyá mi dàgbà!Èmi ìbá rí ọ ní òde,èmi ìbá fi ẹnu kò ọ́ ní ẹnu,wọn kì bá fi mi ṣe ẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 8

Wo Orin Sólómónì 8:1 ni o tọ