Orin Sólómónì 8:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n ọgbà àjàrà mi jẹ́ tèmi, ó wà fún mi;ẹgbẹ̀rún ṣékélì jẹ́ tìrẹ, ìwọ Sólómónì,igba sì jẹ́ ti àwọn alágbàtọ́jú èso.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 8

Wo Orin Sólómónì 8:12 ni o tọ