Orin Sólómónì 8:7 BMY

7 Omi púpọ̀ kò le paná ìfẹ́;Bẹ́ẹ̀ ni gbígbá omi kò le gbá a lọ.Bí ènìyàn bá fún ìfẹ́,ní gbogbo ọrọ̀ ilé rẹ̀,a ó kẹ́gàn rẹ̀ pátapáta.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 8

Wo Orin Sólómónì 8:7 ni o tọ