Rúùtù 1:15 BMY

15 Náómì wí pé, “Wòó, arábìnrin rẹ ti padà lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ̀ àti òrìṣà rẹ̀, ìwọ náà padà pẹ̀lú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:15 ni o tọ