Rúùtù 1:14 BMY

14 Lẹ́ẹ̀kan sí i, wọ́n tún sunkún kíkorò. Nígbà náà ní Órípà fi ẹnu ko ìyá ọkọ rẹ̀ ní ẹnu wí pé ó dìgbà, ṣùgbọ́n Rúùtù dì mọ́ ọn síbẹ̀.

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:14 ni o tọ