Rúùtù 1:20 BMY

20 Náómì sì dáhùn wí pé, “Ẹ má ṣe pè mí ní Náómì. Ẹ pè mí ní Márà (Ìkorò), nítorí wí pé Olódùmarè ti mú kí ayé mi di kíkorò.

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:20 ni o tọ