Rúùtù 4:12 BMY

12 Kí Olúwa fún ọ ní ọmọ tí yóò mú ìdílé rẹ dàbí ti Pérésì, ọmọkùnrin tí Támárì bí fún Júdà láti ipaṣẹ̀ ọ̀dọ́mọbìnrin yìí.”

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:12 ni o tọ