Rúùtù 4:13 BMY

13 Báyìí ni Bóásì ṣe mú Rúùtù, tí ó sì di aya rẹ̀. Nígbà náà ni ó wọlé tọ aya rẹ̀, Olúwa sì mú kí ó lóyùn, ó sì bí ọmọ ọkùnrin kan.

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:13 ni o tọ