Rúùtù 4:14 BMY

14 Àwọn obìnrin sì wí fún Náómì pé, “Ìyìn ni fún Olúwa tí kò fi ọ sílẹ̀ ní òní yìí láìní ìbátan, Olùràpadà. Kí ọmọ náà di olókìkí ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:14 ni o tọ