1 Pétérù 1:10 BMY

10 Ní ti ìgbàlà yìí, àwọn wòlíì tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa oore-ọ̀fẹ́ tí ó mú tọ̀ yín wá, wádìí jinlẹ̀ jinlẹ̀ pẹ̀lú ìbìkítà tí ó ga jùlọ.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 1

Wo 1 Pétérù 1:10 ni o tọ