1 Pétérù 1:18 BMY

18 Níwọ̀nbí ẹ̀yin ti mọ̀ pé a kò fi ohun ìdíbàjẹ́ rà yín pàdà, bí fàdákà tàbí wúrà kúrò nínú ìwà asán yín, tí ẹ̀yin ti jogún láti ọ̀dọ̀ àwọn baba yín.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 1

Wo 1 Pétérù 1:18 ni o tọ