1 Pétérù 2:4 BMY

4 Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin ti tọ̀ ọ́ wá, òkúta ààyè náà, èyí ti àwọn ènìyàn kọ̀ sílẹ̀ ṣùgbọ́n tí Ọlọ́run yàn, òkúta iyebíye.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 2

Wo 1 Pétérù 2:4 ni o tọ