1 Pétérù 3:12 BMY

12 Nítorí ojú Olúwa ń bẹ lára àwọn olódodo,etí rẹ̀ sì ṣí sí ẹ̀bẹ̀ wọn:ṣùgbọ́n ojú Olúwa dojúkọ àwọn tí ń ṣe búburú.”

Ka pipe ipin 1 Pétérù 3

Wo 1 Pétérù 3:12 ni o tọ