1 Pétérù 4:13 BMY

13 Ṣùgbọ́n níwọ̀n bí ẹ̀yin tí jẹ́ alábàápín ìyà Kírísítì, ẹ máa yọ̀, kí ẹ̀yin lè yọ ayọ̀ púpọ̀ nígbà tí a bá fi ògo rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 4

Wo 1 Pétérù 4:13 ni o tọ