2 Kọ́ríńtì 1:7 BMY

7 Àti pé ìrètí wa nípa tiyín dúró ṣinṣin, àwa si mọ̀ pé, bí ẹyin ti jẹ alábápín nínú ìyà wa, bẹ́ẹ̀ ni ẹyin ń pín nínú ìtùnú náà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 1

Wo 2 Kọ́ríńtì 1:7 ni o tọ