2 Kọ́ríńtì 11:16 BMY

16 Mo sì tún wí pé, kí ẹnikẹ́ni má ṣe rò pé òmùgọ̀ ni mí; ṣùgbọ́n bí bẹ́ẹ̀ bá ni, ẹ gbà mí bí òmùgọ̀ kí èmi lè gbé ara mi ga díẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 11

Wo 2 Kọ́ríńtì 11:16 ni o tọ