2 Kọ́ríńtì 11:21 BMY

21 Èmi ń wí lọ́nà ẹ̀gàn, bí ẹni pé àwa jẹ́ aláìlera!Ṣùgbọ́n nínú ohunkóhun tí ẹnìkan ti ní ìgboyà, èmi ń sọ̀rọ̀ bí òmùgọ̀, èmi ní ìgboyà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 11

Wo 2 Kọ́ríńtì 11:21 ni o tọ