2 Kọ́ríńtì 13:14 BMY

14 Oore ọ̀fẹ́ Jésù Kírísítì Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín. (Àmín).

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 13

Wo 2 Kọ́ríńtì 13:14 ni o tọ