2 Kọ́ríńtì 2:15 BMY

15 Nítorí òórùn dídùn Kírísítì ni àwa jẹ́ fún Ọlọ́run, nínú àwọn tí a ń gbàlà àti nínú àwọn tí ó ń ṣègbé:

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 2

Wo 2 Kọ́ríńtì 2:15 ni o tọ