2 Kọ́ríńtì 3:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n ojú-inú wọn fọ́; nítorí pé títí fí di òní olónìí nípa kíka májẹ̀mu láéláé, ìbòjú kan náà sì wà láìká kúrò; nítorí pé nínú Kírísítì ni a tí lè mú ìbòjú náà kúrò.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 3

Wo 2 Kọ́ríńtì 3:14 ni o tọ