2 Kọ́ríńtì 3:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n bí iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí ikú, tí a tí kọ tí a sì ti gbẹ́ sí ara òkúta bá jẹ́ ológo tó bẹẹ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò lè tẹjúmọ́ wíwo ojú Mósè nítorí ògo ojú rẹ̀ (ògo ti ń kọjá lọ);

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 3

Wo 2 Kọ́ríńtì 3:7 ni o tọ