2 Kọ́ríńtì 3:9 BMY

9 Nítorí pé bi iṣẹ́ìrànṣẹ́ ìdálẹ́bi bá jẹ́ ológo, mélòó mélòó ni iṣẹ́ ìrànṣẹ́ òdodo yóò tayọ jù ú ní ògo.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 3

Wo 2 Kọ́ríńtì 3:9 ni o tọ