2 Kọ́ríńtì 4:1 BMY

1 Nitorí náà, níwọ̀n bí ó ti jẹ́ pé nípa àánú Ọlọ́run a rí iṣẹ́ ìránṣẹ́ yìí bí àwa ti rí ní iṣẹ́-ìránṣẹ́ yìí, gẹ́gẹ́ bí a ti fi àánú gbà, àárẹ̀ kò mú wá;

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 4

Wo 2 Kọ́ríńtì 4:1 ni o tọ