2 Kọ́ríńtì 4:14 BMY

14 Àwa mọ̀ pé, ẹni tí o jí Jésù Olúwa dìde yóò sì jí wa dìde pẹ̀lú nípa Jésù, yóò sì mú wa wà níwájú rẹ̀ pẹ̀lú yín

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 4

Wo 2 Kọ́ríńtì 4:14 ni o tọ