2 Kọ́ríńtì 4:18 BMY

18 Níwọ̀n bí kò ti wo ohun tí a ń rí, bí kò ṣé ohun tí a kò rí; nítorí ohun tí a ń rí ni ti ìgbà ìsinsin yìí; ṣùgbọ́n ohun tí a kò rí ni ti ayérayé.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 4

Wo 2 Kọ́ríńtì 4:18 ni o tọ