2 Kọ́ríńtì 4:5 BMY

5 Nítórí àwa kò wàásù àwa tìkárawa, bí kò se Kírísítì Jésù Olúwa; àwa tikarawa sì jẹ́ ẹrú yín nítorí Jésù.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 4

Wo 2 Kọ́ríńtì 4:5 ni o tọ