2 Kọ́ríńtì 5:11 BMY

11 Nítorí náà bí àwa ti mọ ẹ̀rù Olúwa, àwa ń yí ènìyàn lọ́kàn padà; ṣùgbọ́n a ń fí wá hàn fún Ọlọ́run; mo sì gbàgbọ́ pé, a sì ti fì wá hán ní ọkàn yín pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 5

Wo 2 Kọ́ríńtì 5:11 ni o tọ