2 Kọ́ríńtì 5:2 BMY

2 Nítorí nítòótọ́ àwa ń kérora nínú èyí, àwa sì ń fẹ́ gidigidi láti fi ilé wa ti ọ̀run wọ̀ wá.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 5

Wo 2 Kọ́ríńtì 5:2 ni o tọ