2 Kọ́ríńtì 6:10 BMY

10 bí ẹni tí ó kún fún ìbànújẹ́, ṣùgbọ́n àwa ń yọ̀ nígbà gbogbo; bí talákà, ṣùgbọ́n àwa ń sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ dí ọlọ́rọ̀; bí ẹni tí kò ní nǹkan, ṣùgbọ́n àwa ni ohun gbogbo.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6

Wo 2 Kọ́ríńtì 6:10 ni o tọ