2 Kọ́ríńtì 6:17 BMY

17 “Nítorí náà ẹ jáde kúrò láàárin wọn,kí ẹ sì yá ara yín si ọ̀tọ̀,ni Olúwa wí.Ki ẹ má ṣe fi ọwọ kan ohun àìmọ́;Èmi ó sì gbà yín.”

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6

Wo 2 Kọ́ríńtì 6:17 ni o tọ