2 Kọ́ríńtì 6:7 BMY

7 Nínú ọ̀rọ̀ òtítọ́, nínú agbára Ọlọ́run, nínú ìhámọ́ra òdodo ní apá ọ̀tún àti ní apa òsì.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6

Wo 2 Kọ́ríńtì 6:7 ni o tọ