2 Kọ́ríńtì 7:12 BMY

12 Nítorí náà, bí mo tilẹ̀ tí kọ̀wé sí yín, èmi kò kọ ọ́ nítorí ẹni tí ó ṣe ohun búburú náà tàbí nítorí ẹni ti a fi ohun búburú náà ṣe, ṣùgbọ́n kí àníyàn yín nítorí wá lè farahàn níwájú Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 7

Wo 2 Kọ́ríńtì 7:12 ni o tọ