2 Kọ́ríńtì 7:5 BMY

5 Nítorí pé nígbà tí àwa tilẹ̀ dé Makedóníà, ara wá kò balẹ̀, ṣùgbọ́n a ń pọ́n wá lójú níhà gbogbo, ìjà ń bẹ lóde, ẹ̀rù ń bẹ nínú.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 7

Wo 2 Kọ́ríńtì 7:5 ni o tọ