2 Kọ́ríńtì 8:2 BMY

2 Bí ó ti jẹ́ pé dán wọn wò nípa ìpọ́njú, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ayọ̀ àti ìdégóńgó àìní wọn ti kún à kún wọ́ sílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ ìlawọ́ wọn.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 8

Wo 2 Kọ́ríńtì 8:2 ni o tọ