2 Kọ́ríńtì 8:9 BMY

9 Nítorí ẹ̀yin mọ oore-ọ̀fẹ́ Olúwa wa Jésù Kírísítì, pé bí òun ti jẹ́ ọlọ́rọ̀ rí ṣùgbọ́n nítorí yín ó di talákà kí a lè sọ yín di ọlọ́rọ̀ nípa àìní rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 8

Wo 2 Kọ́ríńtì 8:9 ni o tọ