2 Kọ́ríńtì 9:2 BMY

2 Nítorí mo mọ ìmúra tẹ́lẹ̀ yín, èyí tí mo ti ṣògo fún àwọn ará Makedóníà nítorí yín, pé, Ákáyà ti múra tan níwọ̀n ọdún kan tí ó kọjá ìtara yín sì ti rú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sókè.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 9

Wo 2 Kọ́ríńtì 9:2 ni o tọ