2 Tímótíù 1:16 BMY

16 Kí Olúwa fi àánú fún ilé Ònésífórù; nítorí ti ó máa ń tù mi lára nígbà púpọ̀, ẹ̀wọ̀n mi kò sì tì í lójú.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 1

Wo 2 Tímótíù 1:16 ni o tọ