2 Tímótíù 4:1 BMY

1 Nítorí náà mo pàṣẹ fún ọ níwájú Ọlọ́run, àti Kírísítì Jésù, ẹni tí yóò ṣe ìdájọ́ alààyè àti òkú, àti nítorí ìfarahàn rẹ̀ àti ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:1 ni o tọ